Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà Tí A Bá Kú?
A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Bí a kò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi èdè tí ó bóde mu túmọ̀. Níbi tí NW bá ti tẹ̀ lé àyọlò, ó fi hàn pé ìtumọ̀ náà wá láti inú Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures—With References
Orísun Àwòrán:
Ojú ìwé 2: Ààtò ìsìnkú Rábì: ©Brian Hendler 1995. Gbogbo Ẹ̀tọ́ Jẹ́ Tiwọn;
ojú ìwé 6: Iṣẹ́ ọnà láti Íjíbítì: Ẹ̀tọ́ Jẹ́ ti British Museum;
ojú ìwé 7: Socrates: The Metropolitan Museum of Art, Catharine Lorillard Wolfe Collection, Wolfe Fund, 1931. ©The Metropolitan Museum of Art, 1995;
ojú ìwé 13: Parthenon: Larry Lee/H. Armstrong Roberts;
ojú ìwé 14: Alẹkisáńdà Ńlá: Musei Capitolini, Roma;
ojú ìwé 15: Origen: Culver Pictures; St. Augustine: Láti inú ìwé Great Men and Famous Women;
ojú ìwé 16: Avicenna, Averroës: Culver Pictures;
ojú ìwé 17: Ọ̀run àpáàdì: Picture Book of Devils, Demons and Witchcraft/Ernst and Johanna Lehner/Dover;
ojú ìwé 20: Ọ̀nì: Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda onínúure ti Australian International Public Relations; bíárì ilẹ̀ yìnyín: Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda onínúure ti Zoological Society ti San Diego