Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ẹ Máa Ṣọ́nà!
Fún Kí Ni?
Kí Nìdí Tá A Fi Gbọ́dọ̀ Máa Ṣọ́nà Nísinsìnyí?
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò wá látinú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ibi tá a ti rí àwọn Fọ́tò: Ẹ̀yìn ìwé: Àwòrán àgbáyé: A lò ó pẹ̀lú ìyọ̀ǹda The George F. Cram Company, Indianapolis, Indiana; ojú ìwé 3: Òkè: SABAH ARAR/AFP/Getty Images; ìsàlẹ̀: Godo-Foto; ojú ìwé 4: Àìtó oúnjẹ: Fọ́tò UN/DPI látọwọ́ Eskinder Debebe; ogun: UN PHOTO 186705/J. Isaac; ojú ìwé 9: Ọkùnrin tó ń pẹja: © Keith Ross/SuperStock; ojú ìwé 19: Ìdílé tó ń bá àwọn ọmọ kìnnìún ṣeré: Rhino and Lion Park, Gauteng, South Africa; ojú ìwé 20: Fọ́tò AP/Bullit Marquez