Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé
Báwo lo ṣe lè fi hàn pé lóòótọ́ lo fẹ́ràn Ọlọ́run?
Ìgbà wo lo lè ṣe ohun tí ẹ̀rí ọkàn rẹ bá sọ?
Kí ni irú àwọn ọ̀rẹ́ tó o bá yàn ń fi hàn pó o jẹ́?
Kí nìdí tí ọ̀nà tó o gbà ń bọ̀wọ̀ fáwọn aláṣẹ fi máa nípa lórí ojú tí Ọlọ́run á fi máa wò ẹ́?
Kí nìdí tó fi jẹ́ pé àǹfààní tara ẹ ni títẹ̀lé ìlànà Ọlọ́run nípa ìwà tó yẹ ká máa hù wà fún?
Báwo ni iṣẹ́ tó ò ń ṣe ṣe lè mú kó o máa ní ìtẹ́lọ́rùn?
Kí ló máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti máa nífẹ̀ẹ́ Jèhófà?