1 Àwọn Ànímọ́ Jèhófà
2 A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Rẹ Jèhófà
3 “Ọlọ́run Jẹ́ Ìfẹ́”
4 Bá A Ṣe Lè Ní Orúkọ Rere Lọ́dọ̀ Ọlọ́run
5 Kristi, Àwòfiṣàpẹẹrẹ Wa
6 Àdúrà Ìránṣẹ́ Ọlọ́run
7 Ìyàsímímọ́ Kristẹni
8 Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa
9 Ẹ Yin Jèhófà, Ọlọ́run Wa!
10 “Èmi Nìyí! Rán Mi”
11 Mímú Ọkàn Jèhófà Yọ̀
12 Ọlọ́run Ṣèlérí Ìyè Àìnípẹ̀kun
13 Àdúrà Ìdúpẹ́
14 Jèhófà Sọ Ohun Gbogbo Di Tuntun
15 Ìṣẹ̀dá Ń Ṣí Ògo Jèhófà Payá
16 Ẹ Sá Wá Sábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run!
17 Ẹ Tẹ̀ Síwájú Ẹ̀yin Ẹlẹ́rìí!
18 Ìfẹ́ Ọlọ́run Tó Dúró Ṣinṣin
19 Ọlọ́run Ṣèlérí Párádísè
20 Bù Kún Ìpéjọ Wa
21 Aláyọ̀ Ni Àwọn Aláàánú!
22 “Jèhófà Ni Olùṣọ́ Àgùntàn Mi”
23 Jèhófà, Okun Wa
24 Tẹjú Mọ́ Èrè Náà!
25 Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Ọmọ Ẹ̀yìn Kristi Ni Wá
26 Bá Ọlọ́run Rìn!
27 Dúró Sọ́dọ̀ Jèhófà!
28 Orin Tuntun
29 Rírìn Nínú Ìwà Títọ́
30 Jèhófà Bẹ̀rẹ̀ Ìṣàkóso Rẹ̀
31 Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ni Wá!
32 Ẹ Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin!
33 Ẹ Má Bẹ̀rù Wọn!
34 Jíjẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá
35 Ọpẹ́ fún Sùúrù Ọlọ́run
36 “Ohun Tí Ọlọ́rùn Ti So Pọ̀”
37 Ọlọ́run Mí sí Ìwé Mímọ́
38 Ju Ẹrù Ìnira Rẹ Sọ́dọ̀ Jèhófà
39 Àlàáfíà Tó Wà Láàárín Wa
40 Ẹ Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́
41 Sin Jèhófà Nígbà Èwe
42 “Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Tí Wọ́n Jẹ́ Aláìlera”
43 Ẹ Wà Lójúfò, Ẹ Dúró Gbọn-in, Ẹ Di Alágbára
44 Máa Fìdùnnú Kópa Nínú Ìkórè Náà
45 Ẹ Máa Tẹ̀ Síwájú!
46 Jèhófà Ni Ọba Wa!
47 Polongo Ìhìn Rere
48 Bíbá Jèhófà Rìn Lójoojúmọ́
49 Jèhófà Ni Ibi Ìsádi Wa
50 Àpẹẹrẹ Ìfẹ́ Ọlọ́run
51 A Rọ̀ Mọ́ Jèhófà
52 Máa Ṣọ́ Ọkàn Rẹ
53 Ṣíṣiṣẹ́ Pa Pọ̀ ní Ìṣọ̀kan
54 A Ní Láti Nígbàgbọ́
55 Ìyè Àìnípẹ̀kun Nígbẹ̀yìngbẹ́yín!
56 Jọ̀wọ́ Gbọ́ Àdúrà Mi
57 Àṣàrò Ọkàn Mi
58 Àdúrà Ìyàsímímọ́ Mi
59 Ọlọ́run Ni A Ya Ara Wa sí Mímọ́ Fún!
60 Yóò Sọ Ọ́ Di Alágbára
61 Irú Ènìyàn Tó Yẹ Kí N Jẹ́
62 Ti Ta Ni Àwa Jẹ́?
63 Jẹ́ Adúróṣinṣin
64 Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ
65 “Èyí Ni Ọ̀nà”
66 Fífi Gbogbo Ọkàn Sin Jèhófà
67 Máa Gbàdúrà sí Jèhófà Lójoojúmọ́
68 Àdúrà Ẹni Rírẹlẹ̀
69 Mú Mi Mọ Àwọn Ọ̀nà Rẹ
70 “Máa Wádìí Dájú Àwọn Ohun Tí Ó Ṣe Pàtàkì Jù”
71 Ẹ̀mí Mímọ́, Ẹ̀bùn Ọlọ́run
72 Bá A Ṣe Lè Ní Ìfẹ́
73 Ká Nífẹ̀ẹ́ Ara Wa Látọkàn Wá
74 Ìdùnnú Jèhófà
75 Ìdí Ayọ̀ Wa Pọ̀
76 Jèhófà, Ọlọ́run Àlàáfíà
77 Ẹ Máa Dárí Jini
78 Ìpamọ́ra
79 Agbára Inú Rere
80 Ìwà Rere
81 “Fún Wa Ní Ìgbàgbọ́ Sí I”
82 Jẹ́ Onínú Tútù Bíi Kristi
83 Ó Yẹ Ká Ní Ìkóra-Ẹni-Níjàánu
84 “Mo Fẹ́ Bẹ́ẹ̀”
85 Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Èrè Látọ̀dọ̀ Jèhófà
86 Àwọn Obìnrin Olóòótọ́, Àwọn Arábìnrin
87 A Ti Di Ọ̀kan Ṣoṣo
88 Ọmọ Jẹ́ Ohun Ìní Tí Ọlọ́run Fi Síkàáwọ́ Òbí
89 Jèhófà Fìfẹ́ Rọ̀ Ọ́ Pé: “Ọmọ Mi, Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n”
90 Ẹwà Orí Ewú
91 Baba Mi, Ọlọ́run Mi àti Ọ̀rẹ́ Mi
92 “Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà”
93 “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn”
94 Àwọn Ẹ̀bùn Rere Ọlọ́run Tẹ́ Wa Lọ́rùn
95 “Ẹ Tọ́ Ọ Wò, Kí Ẹ sì Rí I Pé Jèhófà Jẹ́ Ẹni Rere”
96 Ẹ Wá Àwọn Ẹni Yíyẹ Kàn
97 Ẹ Tẹ̀ Síwájú, Ẹ̀yin Òjíṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run!
98 Fífúnrúgbìn Èso Ìjọba Ọlọ́run
99 Ẹ Yin Ọba Tuntun Tó Jẹ Lórí Ayé
100 Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Jèhófà Ni Wá!
101 Sísọ Òtítọ́ Ìjọba Ọlọ́run Di Mímọ̀
102 Dara Pọ̀ Nínú Kíkọ Orin Ìjọba Náà!
103 “Láti Ilé dé Ilé”
104 Ẹ Bá Mi Yin Jáà
105 Àwọn Ọ̀run Ń Polongo Ògo Ọlọ́run
106 Bá A Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà
107 Wá sí Òkè Jèhófà
108 Ẹ Yin Jèhófà Nítorí Ìjọba Rẹ̀
109 Yin Àkọ́bí Jèhófà!
110 Àwọn Iṣẹ́ Àgbàyanu Ọlọ́run
111 Òun Yóò Pè
112 Jèhófà, Ọlọ́run Gíga
113 A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Nítorí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀
114 Ìwé Ọlọ́run Jẹ́ Ìṣúra
115 Bá A Ṣe Lè Ṣe Ọ̀nà Wa Ní Rere
116 Ìmọ́lẹ̀ Náà Ń Mọ́lẹ̀ Sí I
117 A Gbọ́dọ̀ Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Jèhófà
118 Ẹ Fìdùnnú Tẹ́wọ́ Gba Ara Yín
119 Ẹ Wá Gba Ìtura!
120 Gbọ́, Ṣègbọràn, Kó O sì Gba Ìbùkún
121 Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí
122 Ẹgbẹẹgbẹ̀rún Àwa Ará
123 Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Jẹ́ Ẹ̀bùnn
124 Gbà Wọ́n Pẹ̀lú Ẹ̀mí Aájò Àlejò
125 Fífi Ìdúróṣinṣin Tẹrí Ba fún Ìṣàkóso Ọlọ́run
126 Òpò Tá A Fi Ìfẹ́ Ṣe
127 Ibi Tá A Ń Fi Orúkọ Rẹ Pè
128 Ipò Nǹkan Ń Yí Pa Dà Ní Ayé Yìí
129 Dídi Ìrètí Wa Mú Ṣinṣin
130 Ìyanu Ni Ìwàláàyè Jẹ́
131 Jèhófà Ń Ṣe Ọ̀nà Àsálà
132 Orin Ìṣẹ́gun
133 Wá Ọlọ́run Kó O Lè Rí Ìgbàlà
134 Fojú Inú Wo Ìgbà Tí Gbogbo Nǹkan Yóò Di Tuntun
135 Fífara Dà Á Dópin