Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
“Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí.”—Sm. 40:8.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní January 2022
Yoruba (od-YR)
© 2005, 2015, 2020
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA