Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
1 Irú Èèyàn Wo Gan-an Ni Mo Jẹ́?
2 Ṣó Yẹ Kí N Máa Da Ara Mi Láàmú Torí Bí Mo Ṣe Rí?
3 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀?
4 Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe tí Mo Bá Ṣàṣìṣe?
5 Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Mi Níléèwé?
6 Kí Ni Mo Lè Ṣe Káwọn Ojúgbà Mi Má Ba Ìwà Mi Jẹ́?
7 Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìbálòpọ̀ Lọ̀ Mí?
8 Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá-Báni-Lòpọ̀?