ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 5
  • Àlàyé Nípa Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àlàyé Nípa Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 5

Àlàyé Nípa Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́

Àpótí ẹ̀kọ́ tó ní nọ́ńbà àti lẹ́tà tá a fi mọ orí tó wà nínú ìwé yìí.

A to àwọn àpótí ẹ̀kọ́ tó wà nínú ìwé yìí tẹ̀ léra lọ́nà tẹ́ ẹ máa fi dá a mọ̀. Bí àpẹẹrẹ, nọ́ńbà tá a kọ sí àpótí mẹ́ta tó wà ní Orí 10 ni 10A, 10B àti 10D. Àwọn tó ń ka ìwé yìí lórí ẹ̀rọ lè rí gbogbo àpótí náà lójú kan ní apá tá a pè ní “Àpótí Ẹ̀kọ́.” Ìwé yìí tún ní àwọn ohun míì tó jẹ́ pé orí ẹ̀rọ nìkan ló wà.

DÉÈTÌ ÌṢẸ̀LẸ̀

Ọ̀pọ̀ lára àwọn àpótí ẹ̀kọ́ inú ìwé yìí ní àwọn déètì ìṣẹ̀lẹ̀. Bó ṣe wà nínú àpẹẹrẹ tó wà nísàlẹ̀ yìí, a ṣẹ́ àwọn ibì kan po lórí ilà inú àwọn déètì ìṣẹ̀lẹ̀ náà kó lè gba ojú ìwé. (Bí àpẹẹrẹ, wo àpótí 8B.) Láwọn ìgbà míì, àwọn ibi tó ṣẹ́ po fi hàn pé a ò mọ bí àkókò náà ṣe pẹ́ tó.​—Wo àpótí 9Ẹ.

Àtẹ déètì ìṣẹ̀lẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 607 Ṣáájú Sànmánì Kristẹni sí ọdún 1914 Sànmánì Kristẹni.

Àwọn ọ̀rọ̀ tí a ké kúrú nínú ìwé yìí:

  • Ṣ.S.K.​—Ṣáájú Sànmánì Kristẹni

  • S.K.​—Sànmánì Kristẹni

  • n.​—nǹkan bíi

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́