ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 9A
Jèhófà Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ—Nígbà Àtijọ́
- 1. Kò ní sí ìbọ̀rìṣà nínú ìjọsìn mímọ́ 
- 2. Wọ́n á pa dà sí ilẹ̀ tó lọ́ràá 
- 3. Jèhófà máa tẹ́wọ́ gba àwọn ọrẹ 
- 4. Àwọn ọkùnrin olóòótọ́ máa múpò iwájú 
- 5. Wọ́n á jọ́sìn Ọlọ́run níṣọ̀kan nínú tẹ́ńpìlì