Friday
“ỌLỌ́RUN TI KỌ́ YÍN LÁTI MÁA NÍFẸ̀Ẹ́ ARA YÍN”—1 TẸSALÓNÍKÀ 4:9
ÒWÚRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 105 àti Àdúrà 
- 9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Nìdí Tí Ìfẹ́ Kò Fi Ní Yẹ̀ Láé? (Róòmù 8:38, 39; 1 Kọ́ríńtì 13:1-3, 8, 13) 
- 10:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Ṣe Gbọ́kàn Lé Àwọn Nǹkan Tó Máa Dópin! - Ọrọ̀ (Mátíù 6:24) 
- Ipò àti Òkìkí (Oníwàásù 2:16; Róòmù 12:16) 
- Ọgbọ́n Èèyàn (Róòmù 12:1, 2) 
- Okun àti Ẹwà (Òwe 31:30; 1 Pétérù 3:3, 4) 
 
- 11:05 Orin 40 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Jèhófà Ń Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn (Jẹ́nẹ́sísì 37:1-36; 39:1–47:12) 
- 11:45 Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Ọmọ Rẹ̀ (Mátíù 25:40; Jòhánù 14:21; 16:27) 
- 12:15 Orin 20 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:25 Fídíò Orin 
- 1:35 Orin 107 
- 1:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Rẹ Yẹ̀ Láé . . . - Bí Wọn Ò Bá Tiẹ̀ Fi Ìfẹ́ Tọ́ Ẹ Dàgbà (Sáàmù 27:10) 
- Bó O Tiẹ̀ Ń Kojú Ìṣòro Níbi Iṣẹ́ (1 Pétérù 2:18-20) 
- Bó O Tiẹ̀ Ń Kojú Ìṣòro Nílé Ìwé (1 Tímótì 4:12) 
- Bó O Tiẹ̀ Ń Ṣàìsàn Tó Le Koko (2 Kọ́ríńtì 12:9, 10) 
- Tó O Bá Tiẹ̀ Jẹ́ Tálákà (Fílípì 4:12, 13) 
- Bí Àwọn Mọ̀lẹ́bí Rẹ Tiẹ̀ Ń Ta Kò Ẹ́ (Mátíù 5:44) 
 
- 2:50 Orin 141 àti Ìfilọ̀ 
- 3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Wa - Àwọn Ọ̀run (Sáàmù 8:3, 4; 33:6) 
- Ayé (Sáàmù 37:29; 115:16) 
- Àwọn Ewéko (Jẹ́nẹ́sísì 1:11, 29; 2:9, 15; Ìṣe 14:16, 17) 
- Àwọn Ẹranko (Jẹ́nẹ́sísì 1:27; Mátíù 6:26) 
- Ara Èèyàn (Sáàmù 139:14; Oníwàásù 3:11) 
 
- 3:55 “Àwọn Tí Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ló Máa Ń Bá Wí” (Hébérù 12:5-11; Sáàmù 19:7, 8, 11) 
- 4:15 “Ẹ Fi Ìfẹ́ Wọ Ara Yín Láṣọ” (Kólósè 3:12-14) 
- 4:50 Orin 130 àti Àdúrà Ìparí