ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 117-118
  • Ọ̀rẹ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọ̀rẹ́
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 117-118

Ọ̀rẹ́

Àwọn wo ló ṣe pàtàkì jù tó yẹ ká mú lọ́rẹ̀ẹ́?

Sm 25:14; Jo 15:13-15; Jem 2:23

Tún wo Owe 3:32

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 5:22-24—Énọ́kù sún mọ́ Ọlọ́run gan-an

    • Jẹ 6:9—Nóà náà bá Ọlọ́run rìn bíi ti baba ńlá ẹ̀, Énọ́kù

Kí nìdí tá a fi nílò àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́?

Owe 13:20; 17:17; 18:24; 27:17

Tún wo Owe 18:1

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Rut 1:16, 17—Rúùtù ò fi Náómì sílẹ̀ nígbà ìṣòro

    • 1Sa 18:1; 19:2, 4—Jónátánì àti Dáfídì di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́

    • 2Ọb 2:2, 4, 6—Èlíṣà fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí ọ̀gá rẹ̀, wòlíì Èlíjà

Kí nìdí tó fi yẹ ká máa pé jọ déédéé pẹ̀lú àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà?

Ro 1:11, 12; Heb 10:24, 25

Tún wo Sm 119:63; 133:1; Owe 27:9; Iṣe 1:13, 14; 1Tẹ 5:11

Báwo la ṣe lè jẹ́ ọ̀rẹ́ tòótọ́, ká sì tún ní àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́?

Lk 6:31; 2Kọ 6:12, 13; Flp 2:3, 4

Tún wo Ro 12:10; Ef 4:31, 32

Kí nìdí tó fi léwu láti máa bá àwọn tí kò nífẹ̀ẹ́ Jèhófà ṣọ̀rẹ́?

Owe 13:20; 1Kọ 15:33; Ef 5:6-9

Tún wo 1Pe 4:3-5; 1Jo 2:15-17

Tún wo “Bíbá Ayé Ṣọ̀rẹ́”

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 34:1, 2—Dínà jìyà torí pé àwọn èèyàn burúkú ló mú lọ́rẹ̀ẹ́

    • 2Kr 18:1-3; 19:1, 2—Jèhófà bá Ọba Jèhóṣáfátì wí torí pé ó bá Áhábù tó jẹ́ ọba búburú ṣọ̀rẹ́

Ṣó yẹ ká yẹra pátápátá fún àwọn tí kò sin Jèhófà?

Mt 28:19, 20; Jo 17:15, 16; 1Kọ 5:9, 10

Kí nìdí tí kò fi yẹ ká fẹ́ ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Wo “Ìgbéyàwó”

Kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa ṣe wọléwọ̀de pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ti mú kúrò nínú ìjọ?

Ro 16:17; 1Kọ 5:11

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́