ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 21-22
  • Àwọn Kristẹni

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Kristẹni
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 21-22

Àwọn Kristẹni

Báwo ló ṣe di pé à ń pé àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù ní Kristẹni?

Iṣe 11:26

Kí la fi ń dá àwọn Kristẹni tòótọ́ mọ̀?

Jo 13:15, 35; 15:17; 1Pe 2:21

Tún wo Ga 5:22, 23; Flp 2:5, 6; 1Jo 2:6; 4:20

Báwo ni Ọlọ́run ṣe gba àwọn Kristẹni tòótọ́ là?

Iṣe 4:12; 1Tẹ 5:9; Ifi 7:10

Tún wo Iṣe 5:30, 31; Ro 6:23

Kí nìdí táwa Kristẹni fi gbà pé Kristi ni ọba wa tá a sì tún ń tẹrí ba fún un?

Da 7:13, 14; Ef 5:24; Flp 2:9, 10; Kol 1:13

Tún wo Sm 2:6; 45:1, 6, 7; Jo 14:23; Ef 1:19-22

Kí nìdí táwa Kristẹnì tòótọ́ kì í fi í ṣe apá kan ayé?

Jo 15:19; Jem 4:4; 1Jo 2:15

Tún wo “Bíbá Ayé Ṣọ̀rẹ́” àti “Ìjọba—Àwa Kristẹni Kì Í Dá Sí Ogun àti Ọ̀rọ̀ Òṣèlú”

Kí nìdí táwa Kristẹni tòótọ́ fi ń tẹ̀ lé òfin ìjọba?

Ro 13:1, 6, 7; Tit 3:1; 1Pe 2:13, 14

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 22:15-22—Jésù sọ ìdí tó fi yẹ káwọn ọmọ ẹ̀yìn ẹ̀ máa san owó orí

    • Iṣe 4:19, 20; 5:27-29—Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù fi hàn pé àwọn ṣe tán láti máa tẹ̀ lé òfin ìjọba tí kò bá ṣàá ti ta ko òfin Ọlọ́run

Ọ̀nà wo làwa Kristẹni gbà jẹ́ ọmọ ogun?

2Kọ 10:4; 2Ti 2:3

Tún wo Ef 6:12, 13; 1Ti 1:18

Kí nìdí tó fi yẹ kí ìwà àwa Kristẹni bá ohun tá à ń kọ́ mu?

Mt 5:16; Tit 2:6-8; 1Pe 2:12

Tún wo Ef 4:17, 19-24; Jem 3:13

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Iṣe 9:1, 2; 19:9, 23—Ìgbà kan wà tí wọ́n ń pe ẹ̀sìn Kristẹni ní “Ọ̀nà Náà,” èyí jẹ́ ká rí i pé ó gbọ́dọ̀ hàn nínú gbogbo ohun tá à ń ṣe pé ọmọ ẹ̀yìn Kristi ni wá

Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni tòótọ́ jẹ́ Ẹlẹ́rìí fún Jèhófà Ọlọ́run?

Ais 43:10, 12; Jo 17:6, 26; Ro 15:5, 6; Ifi 3:14

Tún wo Heb 13:15

Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni tòótọ́ tún máa jẹ́rìí nípa Jésù Kristi?

Iṣe 1:8; 5:42; 10:40-42; 18:5; Ifi 12:17

Tún wo Iṣe 5:30, 32; 13:31

Kí nìdí tó fi yẹ kí gbogbo Kristẹni tòótọ́ máa wàásù ìhìn rere?

Mt 28:19, 20; Lk 10:9; Ro 10:9, 10; Ifi 22:17

Tún wo Ais 61:1; 1Kọ 9:16

Ṣé ó yẹ káwa Kristẹni máa bẹ̀rù inúnibíni?

Wo “Inúnibíni”

Ṣé gbogbo Kristẹni tòótọ́ ló máa lọ bá Jésù Kristi jọba lọ́run?

Lk 12:32; Ifi 7:3, 4; 14:1

Tún wo 1Pe 1:3, 4

Ibo ni èyí tó pọ̀ jù lára àwọn Kristẹni tòótọ́ ti máa gbádùn ìyè àìnípẹ̀kun?

Sm 37:29; Ifi 7:9, 10; 21:3, 4

Ṣé a lè rí Kristẹni tòótọ́ nínú àwọn ẹ̀sìn tó ń pera wọn ní Kristẹni lónìí?

Jo 10:16; 17:20, 21; 1Kọ 1:10

Ṣé gbogbo àwọn tó ń pera wọn ní Kristẹni ni ọmọlẹ́yìn Jésù lóòótọ́?

Mt 7:21-23; Ro 16:17, 18; 2Kọ 11:13-15; 2Pe 2:1

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 13:24-30, 36-43—Jésù sọ àpéjúwe kan tó fi hàn pé àwọn ayédèrú Kristẹni máa pọ̀

    • 2Kọ 11:24-26—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé “àwọn èké arákùnrin” wà lára àwọn tó mú kí nǹkan nira fóun

    • 1Jo 2:18, 19—Àpọ́sítélì Jòhánù kìlọ̀ pé “ọ̀pọ̀ aṣòdì sí Kristi” ló ti kúrò nínú òtítọ́

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́