ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 73
  • Irọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Irọ́
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 73

Irọ́

Ojú wo ni Jèhófà fi ń wo àwọn tó máa ń parọ́ tàbí tó máa ń yẹ àdéhùn?

Ro 1:31, 32

Tún wo Sm 15:4; Mt 5:37

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Ẹk 9:27, 28, 34, 35—Fáráò sọ pé òun máa jẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì lọ, àmọ́ kò mú ìlérí ẹ̀ ṣẹ

    • Isk 17:11-15, 19, 20—Jèhófà fìyà jẹ Ọba Sedekáyà torí pé kò mú ìlérí tó ṣe fún ọba Bábílónì ṣẹ

    • Iṣe 5:1-10—Ananáyà àti Sàfírà sọ pé gbogbo owó táwọn rí nígbà táwọn ta ilẹ̀ àwọn làwọn kó wá fún ìjọ

Ojú wo ni Jèhófà fi ń wo àwọn tó máa ń ba àwọn míì jẹ́?

Sm 15:1-3; Owe 6:16-19; 16:28; Kol 3:9

Tún wo Owe 11:13; 1Ti 3:11

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 2Sa 16:1-4; 19:24-30—Olóòótọ́ èèyàn ni Méfíbóṣétì, àmọ́ Síbà tó jẹ́ ìránṣẹ́ ẹ̀ bà á jẹ́ lójú Dáfídì

    • Ifi 12:9, 10—Èṣù tó jẹ́ abanijẹ́ ń fẹ̀sùn kan àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run tọ̀sántòru

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́