ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 119-120
  • Sùúrù

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sùúrù
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 119-120

Sùúrù

Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ní sùúrù?

Ro 2:4; 9:22

Tún wo Ne 9:30

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jer 7:23-25—Jèhófà jẹ́ ká mọ ìgbà tóun ti ń fara dà á bọ̀ fáwọn èèyàn òun tí wọ́n ya aláìgbọràn

    • 2Pe 3:3-9, 15—Àpọ́sítélì Pétérù sọ bí sùúrù Jèhófà ṣe pọ̀ tó àti ìdí tó fi máa ń ní sùúrù, àmọ́ ó sọ pé sùúrù Jèhófà máa dópin lọ́jọ́ kan

Kí nìdí tó fi yẹ ká kọ́ bá a ṣe lè máa ní sùúrù?

Owe 25:15; Ef 4:1-3; 2Ti 2:24, 25; 4:2

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 39:19-21; 40:14, 15, 23; 41:1, 9-14 —Bó tiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ta Jósẹ́fù sóko ẹrú ní Íjíbítì, tí wọ́n hùwà àìdáa sí i, tí wọ́n sì fi í sẹ́wọ̀n fọ́pọ̀ ọdún, ó ní sùúrù, ó ń fara dà á, ìyẹn sì jẹ́ kí ìgbàgbọ́ ẹ̀ túbọ̀ lágbára

    • Heb 6:10-15—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù fi àpẹẹrẹ Àbúráhámù kọ́ àwa Kristẹni pé ó ṣe pàtàkì ká máa ní sùúrù

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́