ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 35
  • Eré Ìnàjú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Eré Ìnàjú
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 35

Eré Ìnàjú

Ṣó burú táwa Kristẹni bá wáyè láti sinmi, ká sì tún gbádùn ara wa?

Onw 2:24; 3:12, 13; 4:6

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mk 6:31, 32—Ọwọ́ Jésù máa ń dí gan-an, síbẹ̀ ó ní kí òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn òun wá ibì kan tó pa rọ́rọ́ kí wọ́n lè sinmi

Àwọn ìlànà Bíbélì wo ló lè ràn wá lọ́wọ́ tá ò fi ní máa ṣeré ìnàjú débi pé a ò ní ráyè àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ ìjọsìn Jèhófà mọ́?

Mt 6:21, 33; Ef 5:15-17; Flp 1:9, 10; 1Ti 4:8

Tún wo Owe 21:17; Onw 7:4

Kí nìdí tó fi yẹ ká yẹra fáwọn eré ìnàjú tó ń gbé ìṣekúṣe lárugẹ?

1Kọ 6:18; Ef 5:3, 4; Kol 3:5; Jem 1:14, 15

Kí nìdí tó fi yẹ ká yẹra fáwọn eré ìnàjú tó ń gbé ìbínú àti ẹ̀mí ìdíje lárugẹ?

Onw 4:4; Ga 5:26; 6:4

Kí nìdí tó fi yẹ ká yẹra fáwọn eré ìnàjú tó ń gbé ìwà ipá lárugẹ?

Sm 11:5; Owe 3:31; 6:16, 17

Báwo làwa Kristẹni ṣe lè mọ àwọn nǹkan tí kò yẹ ká máa fi dápàárá?

Owe 15:21; 26:18, 19; Ef 5:3, 4

Kí nìdí tó fi yẹ ká máa gba tàwọn míì rò ká tó pinnu irú eré ìnàjú tá a máa ṣe?

Ro 14:13, 21; 1Kọ 8:13; 10:24

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́