Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- 1. Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì àǹfààní tá a ní láti wà nínú ìdílé Jèhófà? (Éfé. 4:3) 
- 2. Báwo la ṣe lè mára tu àwọn míì, kí sì nìdí tó fi yẹ ká ṣe bẹ́ẹ̀? (Róòmù 15:7) 
- 3. Báwo la ṣe lè ran ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́wọ́ láti di ara ìdílé Jèhófà? (Éfé. 2:17; 6:15) 
- 4. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí àlàáfíà máa wà? (Éfé. 4:29; 5:1, 2; 6:13) 
- 5. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí ìfẹ́ tá a ní fún ìdílé wa nípa tẹ̀mí jinlẹ̀ sí i? (Éfé. 1:15, 16) 
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-copgm23-YR