Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Máa Ṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́—2024
Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti Ọdún Yìí “Nígbà tí ẹ̀rù ń bà mí, mo gbẹ́kẹ̀ lé ọ.”—Sáàmù 56:3.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní June 2023
Yoruba (es24-YR)
© 2023
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA