Iwọ Yoo Ha Fẹ́ Kí A Bẹ̀ Ọ́ Wò Bí?
Àní ninu ayé onídààmú yii, iwọ lè jèrè ayọ̀ lati inú ìmọ̀ pípéye Bibeli nípa Ọlọrun, Ìjọba rẹ̀, ati ète àgbàyanu rẹ̀ fún aráyé. Bí iwọ yoo bá fẹ́ lati gba ìsọfúnni síwájú síi tabi bí iwọ yoo bá fẹ́ kí ẹnìkan kàn sí ọ lati darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bibeli inú ilé lọ́fẹ̀ẹ́ pẹlu rẹ, jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Watch Tower, P.M.B. 1090, Benin City, Edo State, tabi sí àdírẹ́sì tí ó ṣe wẹ́kú tí a tò sí ojú-ìwé 2.