ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w08 8/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
w08 8/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Ìdí mẹ́rin wo ló wà tó o fi lè gba ìlérí tí Bíbélì ṣe nípa ọjọ́ iwájú gbọ́? Wo ojú ìwé 8.

◼ Báwo lo ṣe lè bá ọmọ tó ti bàlágà tí kò fẹ́ dáhùn àwọn ìbéèrè tó o bá bi í sọ̀rọ̀? Wo ojú ìwé 11.

◼ Àwọn ìgbésẹ̀ wo làwọn òbí lè gbé tó máa jẹ́ káwọn ọmọ wọn lè máa fi hàn pé àwọn moore? Wo ojú ìwé 13.

◼ Ǹjẹ́ Jésù lo orúkọ Ọlọ́run nígbà tó ń wàásù fáwọn tí wọ́n jọ jẹ́ Júù? Wo ojú ìwé 19.

◼ Kí ló mú kí ọ̀dọ́ kan tó wà nínú ẹgbẹ́ àwọn ọmọọ̀ta kan tí wọ́n ń pè ní Àwọn Ọmọ Èṣù (Junior Satans) nílẹ̀ Mẹ́síkò ṣe ìyípadà ńláǹlà sí ọ̀nà ìgbésí ayé rẹ̀? Wo ojú ìwé 28.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́