ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w09 5/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
w09 5/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Ẹ̀rí wo ló fi hàn pé Jésù ti gbé láyé rí? Wo ojú ìwé 7.

◼ Tó o bá ń ṣiyèméjì nípa Ọlọ́run, kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé kó o wá ìdáhùn tó máa tẹ́ ẹ lọ́rùn? Wo ojú ìwé 9.

◼ Báwo lo ṣe lè ran ọmọ ẹ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń bàlágà lọ́wọ́ kó lè kojú àwọn ìṣòro tó bá ní lọ́jọ́ iwájú? Wo ojú ìwé 10 sí 12.

◼ Báwo làwọn ẹ̀mí búburú ṣe lè ṣe ẹ́ níkà? Wo ojú ìwé 20.

◼ Ṣé Ọlọ́run ló ń fáwọn èèyàn lágbára láti máa ṣèwòsàn lọ́nà ìyanu lóde òní? Wo ojú ìwé 28.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́