ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w09 12/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
w09 12/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Kà nípa ojútùú tó máa kárí ayé sí àwọn ìṣòro tó kárí ayé lóde òní. Wo ojú ìwé 5.

◼ Àwọn tó là á já níléèwé tí ẹnì kan ti yìnbọn pa àwọn èèyàn nílùú Winnenden lórílẹ̀-èdè Jámánì sọ bí wọ́n ṣe fara dà á lẹ́yìn ìpakúpa náà. Wo ojú ìwé 9.

◼ Ta ni Hẹ́rọ́dù Ọba tó fẹ́ pa Jésù nígbà tí Jésù ṣì wà ní ọmọ ọwọ́? Wo ojú ìwé 13.

◼ Kí lo mọ̀ nípa Ọdún Tuntun tí àwọn ará Ìlà Oòrùn Ayé máa ń ṣe? Wo ojú ìwé 20.

◼ Kà nípa orin kíkọ láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì nípa ṣíṣàyẹ̀wò ìgbésí ayé Dáfídì Ọba. Wo ojú ìwé 26.

◼ Ṣé lóòótọ́ ni àwọn ọba tàbí amòye mẹ́ta wá jọ́sìn Jésù nígbà tó wà ní ibùjẹ ẹran? Wo ojú ìwé 31.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]

Àwọn Ọmọ tí ebi ń pa: àjọ WHO/OXFAM

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́