Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2017
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
- A Ó Bù Kún Ẹni Tí Ó Jẹ́ Ọ̀làwọ́ (ọrẹ), Nov. 
- Ayọ̀ Tó Wà Nínú Kéèyàn Jẹ́ Kí Ohun Ìní Díẹ̀ Tẹ́ Òun Lọ́rùn, May 
- Bí Ara Ẹ Ṣe Lè Mọlé Nínú Ìjọ Tó O Wà Báyìí, Nov. 
- “Ìgbà Wo La Tún Máa Ṣe Àpéjọ Míì?” (Mẹ́síkò), Aug. 
- “Kò Sí Ọ̀nà Tó Burú Jù Tàbí Jìn Jù” (Ọsirélíà), Feb. 
- Oore Kan Tó Sèso Rere, Oct. 
- ‘Wọ́n Fìtara Wàásù Ju Ti Tẹ́lẹ̀ Lọ’ (àpéjọ àgbègbè ọdún 1922), May 
- Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Tọ́kì, July 
- Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú (àwọn arábìnrin tí kò tíì lọ́kọ), Jan. 
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
- ‘Àlàáfíà Ọlọ́run Ta Gbogbo Ìrònú Yọ,’ Aug. 
- Àwọn Kẹ̀kẹ́ Ẹṣin àti Adé Kan Ń Dáàbò Bò Ẹ́, Oct. 
- Àwọn Nǹkan Wo Ló Máa Lọ tí Ìjọba Ọlọ́run Bá Dé? Apr. 
- Bá A Ṣe Lè Bọ́ Àwọn Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀, Ká Má sì Gbé E Wọ̀ Mọ́, Aug. 
- Bá A Ṣe Lè Gbé Àkópọ̀ Ìwà Tuntun Wọ̀, Tá Ò sì Ní Bọ́ Ọ Sílẹ̀ Mọ́, Aug. 
- Bá A Ṣe Lè Ní Ọrọ̀ Tòótọ́, July 
- Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Àjèjì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Máa ‘Fayọ̀ Sin Jèhófà,’ May 
- Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Fáwọn Ọmọ Tí Òbí Wọn Jẹ́ Àjèjì, May 
- Bí Àwọn Ìran Tí Sekaráyà Rí Ṣe Kàn Ẹ́, Oct. 
- Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Yín Di Tútù, May 
- Ẹ Máa Bọlá fún Àwọn Tí Ọlá Tọ́ Sí, Mar. 
- ‘Ẹ Máa Sunkún Pẹ̀lú Àwọn Tí Ń Sunkún,’ July 
- Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè “Di Ọlọ́gbọ́n fún Ìgbàlà,” Dec. 
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—“Ẹ Máa Ṣiṣẹ́ Ìgbàlà Yín Yọrí,” Dec. 
- Fara Mọ́ Ìṣàkóso Jèhófà! June 
- Fi ‘Nǹkan Wọ̀nyí Lé Àwọn Olùṣòtítọ́ Lọ́wọ́,’ Jan. 
- Fi Ọkàn Pípé Pérépéré Sin Jèhófà! Mar. 
- “Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Kí O sì Máa Ṣe Rere,” Jan. 
- Idà Ni Òtítọ́ Ń Mú Wá, Kì Í Ṣe Àlàáfíà, Oct. 
- Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Ẹni Tó Mẹ̀tọ́mọ̀wà, Jan. 
- Ìràpadà—“Ọrẹ Pípé” Tí Baba Fún Wa, Feb. 
- “Ìwọ Ha Nífẹ̀ẹ́ Mi Ju Ìwọ̀nyí Lọ Bí?” May 
- Jèhófà Máa Jẹ́ Kí Àwọn Ìpinnu Rẹ Yọrí Sí Rere, July 
- Jèhófà Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀, Feb. 
- Jèhófà Ń Tù Wá Nínú Nínú Gbogbo Ìpọ́njú Wa, June 
- “Jẹ́ Onígboyà . . . Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀” Sept. 
- “Kí A Nífẹ̀ẹ́ . . . ní Ìṣe àti Òtítọ́,” Oct. 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Yin Jèhófà? July 
- Lo Ìgbàgbọ́ Kó O Lè Ṣe Ìpinnu Tó Mọ́gbọ́n Dání! Mar. 
- Má Ṣe Fàyè Gba Èrò Ayé, Nov. 
- Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun Mú Kó O Pàdánù Èrè Ọjọ́ Iwájú, Nov. 
- Máa Fàánú Hàn Bíi Ti Jèhófà, Sept. 
- Máa Fàánú Hàn, Kó O sì Máa Ṣe Ìdájọ́ Òdodo Bíi Ti Jèhófà, Nov. 
- Máa Fi Ayọ̀ Kọrin! Nov. 
- Máa Fọkàn sí Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí, June 
- Máa Kó Ara Rẹ Níjàánu, Sept. 
- “Mo Mọ̀ Pé Yóò Dìde,” Dec. 
- “Mo Ní Ìrètí Sọ́dọ̀ Ọlọ́run,” Dec. 
- Mọyì Òmìnira Tó O Ní, Jan. 
- O Lè Jẹ́ Amẹ̀tọ́mọ̀wà Bí Kò Bá Tiẹ̀ Rọrùn, Jan. 
- Ohun Tí Jèhófà Ní Lọ́kàn Máa Ṣẹ! Feb. 
- “Ohun Tí O Jẹ́jẹ̀ẹ́, San Án,” Apr. 
- ‘Onídàájọ́ Ilẹ̀ Ayé’ Máa Ń Ṣe Ohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo, Apr. 
- “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run . . . Ń Sa Agbára,” Sept. 
- Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Yóò Wà Títí Láé, Sept. 
- Pọkàn Pọ̀ Sórí Ọ̀rọ̀ Tó Ṣe Pàtàkì Jù, June 
- Ṣé Èrò Tí Jèhófà Ní Nípa Ìdájọ́ Òdodo Ni Ìwọ Náà Ní? Apr. 
- Ṣé Ò Ń Sá Di Jèhófà? Nov. 
- Ṣé Wàá Fọkàn sí Àwọn Ohun Tá A Ti Kọ Sílẹ̀? Mar. 
- Ṣé Wàá Lè Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà? Aug. 
- Ta Ló Ń Darí Àwa Èèyàn Ọlọ́run Lónìí? Feb. 
- Yọ̀ǹda Ara Rẹ Tinútinú, Kí Ìyìn Lè Jẹ́ ti Jèhófà! Apr. 
BÍBÉLÌ
- Bó O Ṣe Lè Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Látinú Kíka Bíbélì, No. 1 
- Elias Hutter Ṣiṣẹ́ Ribiribi Sínú Àwọn Bíbélì Èdè Hébérù Tó Ṣe, No. 4 
- Ewu Tó Wà Nínú Kéèyàn Ṣi Bíbélì Lóye, No. 1 
- Ẹ̀rí Míì Tún Rèé (Táténáì wà lóòótọ́), No. 3 
- Kí Nìdí Tí Oríṣiríṣi Bíbélì Fi Wà? No. 6 
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
- Mi Ò Fẹ́ Kú O! (Y. Quarrie), No. 1 
- Mo Fẹ́ràn Baseball Gan-an! (S. Hamilton), No. 3 
- Ní Tèmi O, Kò Sí Ọlọ́run (A. Golec), No. 5 
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
- Jèhófà Kò Ní “Jẹ́ Kí A Dẹ Yín Wò Ré Kọjá Ohun Tí Ẹ Lè Mú Mọ́ra” (1Kọ 10:13), Feb. 
- Kí Nìdí Tí Ohun Tí Mátíù àti Lúùkù Sọ Nípa Ìgbà Tí Jésù Wà Ní Kékeré Fi Yàtọ̀ Síra? Aug. 
- Ǹjẹ́ Àwọn Tọkọtaya Kristẹni Lè Lo Ìfètòsọ́mọbíbí Kan Tí Wọ́n Ń Pè Ní IUD? Dec. 
- Ṣé Ìgbà Gbogbo Ni Ìlà Ìdílé Tí Mèsáyà Ti Wá Máa Ń Gba Ọ̀dọ̀ Àkọ́bí Ọkùnrin Kọjá? Dec. 
- Ṣé Ó Yẹ Kí Kristẹni Ní Ìbọn? July 
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
- Èrè Tó Wà Nínú Fífúnni, No. 2 
- Èrò Tó Yẹ Ká Ní Nípa Àṣìṣe, No. 6 
- Ìfẹ́—Ànímọ́ Kan Tó Ṣe Pàtàkì, Aug. 
- Má Ṣe Jẹ́ Kí Sátánì Tàn Ẹ́ Jẹ, July 
- Ṣé Ó Pọn Dandan Kí Kristẹni Òjíṣẹ́ Wà Láìgbéyàwó? No. 2 
- Ṣé Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Ṣe Ọdún Kérésìmesì? No. 6 
- Tí Àárín Ìwọ àti Ọ̀rẹ́ Rẹ Bá Fẹ́ Dàrú, Mar. 
- Yanjú Èdèkòyédè Kí Àlàáfíà Lè Jọba, June 
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
- A Fara Da Ìpọ́njú, Jèhófà sì Bù Kún Wa (P. Sivulsky), Aug. 
- Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Adití, Mò Ń Kọ́ Àwọn Míì Lẹ́kọ̀ọ́ (W. Markin), May 
- Inú Mi Dùn Pé Mo Bá Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ṣiṣẹ́ (D. Sinclair), Sept. 
- Jèhófà Fi Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Hàn sí Wa Lónírúurú Ọ̀nà (D. Guest), Feb. 
- Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ṣe Ìfẹ́ Rẹ̀ (O. Matthews), Oct. 
- Mo Bá Àwọn Ọlọ́gbọ́n Rìn, Mo sì Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Wọn (W. Samuelson), Mar. 
- Mo Fi Àwọn Nǹkan Sílẹ̀ Kí N Lè Tẹ̀ Lé Jésù (F. Fajardo), Dec. 
- Mo Pinnu Pé Ọmọ Ogun Kristi Ni Màá Jẹ́ (D. Psarras), Apr. 
JÈHÓFÀ
JÉSÙ KRISTI
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
- Àbá Tí Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Fún Àwọn Atukọ̀ Òkun (Iṣe 27), No. 5 
- Àníyàn, No. 4 
- Báwo Ni Wọ́n Ṣe Ń Mú Iná Láti Ibì Kan dé Ibòmíì Láyé Àtijọ́? Jan. 
- Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́, May 
- Ẹ̀bùn Tó Dáa Ju Gbogbo Ẹ̀bùn Lọ, No. 6 
- Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin, No. 3 
- ‘Ìbùkún Ni fún Ìlóyenínú Rẹ’ (Ábígẹ́lì), June 
- Ìjìyà, No. 1 
- Jósẹ́fù ará Arimatíà, Oct. 
- Kí Ni Amágẹ́dọ́nì? No. 6 
- Kí Nìdí Tí Jésù Fi Dẹ́bi fún Àwọn Tó Ń Búra? Oct. 
- Lẹ́tà Èdè Hébérù Tó Kéré Jù Lọ, No. 4 
- Ǹjẹ́ Àkókò Kan Ń Bọ̀ Tí Gbogbo Èèyàn Á Máa Ṣe Ìdájọ́ Òdodo? No. 3 
- Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìyè àti Ikú, No. 4 
- “O Jẹ́ Obìnrin Kan Tí Ó Lẹ́wà ní Ìrísí” (Sárà), No. 3 
- Orúkọ Bíbélì Kan Tó Wà Lára Ìkòkò, Mar. 
- “Ó Ti Wu Ọlọ́run Dáadáa” (Énọ́kù), No. 1 
- Òwò Ẹrú, No. 2 
- Ọkàn Àwọn Èèyàn Ló Ṣe Pàtàkì, June 
- Ọlọ́run Pè É Ní “Ìyá Ọba” (Sárà), No. 5 
- Ṣé Àlááfíà Ṣì Máa Wà Láyé? No. 5 
- Ṣé Àwọn Áńgẹ́lì Wà Lóòótọ́? No. 5 
- Ṣé “Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn” Là Ń Gbé Báyìí? No. 2 
- Ṣé Ayé Máa Di Párádísè Lóòótọ́? No. 4 
- Ṣé Lóòótọ́ La Lè Pe Àwọn Oníṣòwò Tó Ń Tajà Nínú Tẹ́ńpìlì Jerúsálẹ́mù Ní “Ọlọ́ṣà”? June 
- Tí Àìsàn Gbẹ̀mí-Gbẹ̀mí Bá Ń Ṣe Ẹni Tá A Nífẹ̀ẹ́, No. 4