Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: FEBRUARY 26–APRIL 1, 2018
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
BÒLÍFÍÀ
Nílùú Riberalta ní ìpínlẹ̀ Beni, àwọn tọkọtaya aṣáájú-ọ̀nà méjì ń kó àwọn ìtẹ̀jáde wa sínú ọkọ̀ òfuurufú. Wọ́n ń lọ síbi àdádó kan lórílẹ̀-èdè yẹn láti lọ wàásù
IYE AKÉDE
26,081
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
42,568
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
75,027
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.