Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
May 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JULY 9–AUGUST 5, 2018
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
SIERRA LEONE
Àwọn aṣáájú-ọ̀nà méjì ń fún obìnrin kan ní àṣàrò kúkúrú nílùú Freetown, lásìkò tí òjò máa ń rọ̀ gan-an
IYE AKÉDE
2,171
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
5,291
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
8,831
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.