Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 494 134.8 12.9 59.5 10.8
Aṣá. Déédéé 23,496 58.2 7.0 22.3 5.4
Aṣá. Olù. 8,010 48.9 4.6 15.2 3.7
Akéde 194,353 10.6 1.0 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 226,353 Àwọn Tí A Batisí: 374
A láyọ̀ láti ròyìn góńgó tó ju ti ìgbàkigbà rí lọ ti 226,353 akéde ní oṣù August. Àròpọ̀ àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tí wọ́n jẹ́ 23,496 jẹ́ góńgó tuntun pẹ̀lú. Bó ṣe jẹ́ pé góńg̣ó tuntun la ní nínú ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó jẹ́ 363,771, ó dájú pé, ó ṣeé ṣe kí a túbọ̀ pọ̀ sí i lọ́jọ́ iwájú.