Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn December
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 422 130.6 15.2 58.2 10.3
Aṣá. Déédéé 24,150 55.1 7.7 20.9 5.2
Aṣá. Olù. 6,952 47.8 4.9 13.6 3.5
Akéde 190,639 10.2 1.1 3.4 1.0
ÀRÒPỌ̀ 222,163 Àwọn Tí A Batisí: 4,062
A tún ti ní iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tó pọ̀ ju ti ìgbàkígbà rí lọ lóṣù December. Àròpọ̀ iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tí wọ́n jẹ́ 24,150 tí wọ́n ròyìn fi mẹ́tàdínláàádọ́ta pọ̀ ju iye àwọn táa ní lóṣù November 1999, tí wọ́n jẹ́ 24,103.