Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a ó fi lọni ní oṣù June: Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? tàbí Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. Fún bíbẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé láfiyèsí pàtàkì. July: A lè lo èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n tó tẹ̀ lé e yìí: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Gbádùn Iwalaaye lori Ilẹ Ayé Titilae!, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?, Ìwọ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run!, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Báwo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà tí A Bá Kú?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú, Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi? àti “Sawo O! Emi Nsọ Ohun Gbogbo Di Ọtun.” Àwọn ìwé pẹlẹbẹ náà, Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi?, àti Ìwé Kan Tí Ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn ni a lè fi lọni tó bá yẹ. August àti September: Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. (Bí èyí kò bá sí, a lè fi ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tọ́jọ́ rẹ̀ ti pẹ́ lọni.)
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tó Wà Báyìí fún Àwọn Afọ́jú:
Ṣíṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́ Lójoojúmọ́—2001 (ìwé mẹ́rin) —Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì! (ìwé mẹ́ta) —Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní (ìwé mẹ́rin) —Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Iṣetojọ Lati Ṣaṣepari Iṣẹ-ojiṣẹ Wa (ìwé mẹ́rin; kìkì àwọn akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi ló wà fún) —Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Ìwọ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run (ìwé kan) —Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Ẹ jọ̀wọ́, nígbà tí ẹ bá ń béèrè àwọn ìtẹ̀jáde tó jẹ́ ti àwọn afọ́jú, fọ́ọ̀mù Literature Request Form (S-14), mìíràn ni kí ẹ lò, kí ẹ sì kọ “BRAILLE REQUEST” sórí rẹ̀ gàdàgbàgàdàgbà.
Kí ẹ fi àwọn ìbéèrè tí ẹ bá ní nípa àwọn ìtẹ̀jáde tó jẹ́ ti àwọn afọ́jú ránṣẹ́ sí ẹ̀ka: BRAILLE DESK.