Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn July
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 534 134.1 22.3 63.6 12.9
Aṣá. Déédéé 27,084 50.9 9.0 19.6 5.3
Aṣá. Olù. 4,267 45.7 7.3 14.3 3.8
Akéde 210,869 10.0 2.0 3.6 1.1
ÀRÒPỌ̀ 242,754 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 348
Ní oṣù July, iye àwa akéde tún pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ, a jẹ́ 242,754. A fi 1,841 kọjá iye tá a jẹ́ tẹ́lẹ̀ ní oṣù April. A tún ní iye tí ó pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ nínú iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé àti nínú iye ìwé kékeré pẹ̀lú ìwé pẹlẹbẹ. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà nítorí ìbùkún rẹ̀ lórí àwọn ìgbòkègbodò wa.