Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a ó fi lọni ní oṣù June: Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? tàbí Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. Fi sọ́kàn pé o fẹ́ bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. July sí September: A lè fi èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé 32 tó tẹ̀ lé e yìí lọni: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Gbádùn Iwalaaye Lori Ilẹ Ayé Titilae!, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà Tí A Bá Kú?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú?, Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi? àti “Sawo O! Emi Nsọ Ohun Gbogbo Di Ọtun.” A tún lè fi àwọn ìwé pẹlẹbẹ wọ̀nyí, Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi?, Ìwé Kan Tí Ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn, àti Ìwọ́ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run lọni níbi tó bá ti bá àkókò mu.
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tuntun Tó Wà: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Onílẹ́tà Gàdàgbà—Gẹ̀ẹ́sì
Ìdìpọ̀ Ilé Ìṣọ́ ọdún 2001—Gẹ̀ẹ́sì
◼ Kásẹ́ẹ̀tì Àfetígbọ́ Tuntun Tó Wà: Respect Jehovah’s Authority—On Audiocassette (Àwòkẹ́kọ̀ọ́, kásẹ́ẹ̀tì ẹyọ kan)—Gẹ̀ẹ́sì
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tó Wà Báyìí fún Àwọn Afọ́jú: Jehovah’s Witnesses—Proclaimers of God’s Kingdom (ìdìpọ̀ méje)—Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Mankind’s Search for God (ìdìpọ̀ mẹ́rin)—Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Reasoning From the Scriptures (ìdìpọ̀ mẹ́rin)—Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Revelation—Its Grand Climax At Hand! (ìdìpọ̀ mẹ́fà)—Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
All Scripture Is Inspired of God and Beneficial (ìdìpọ̀ méje)—Èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìpele kejì
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ ọ̀rọ̀ náà, ATTENTION: BRAILLE DESK sórí ìwé tẹ́ ẹ bá fi béèrè fún àwọn ìtẹ̀jáde tó jẹ́ ti àwọn afọ́jú. Kí ẹ sì kọ orúkọ ẹni tó fẹ́ kà á àti àdírẹ́sì onítọ̀hún ránṣẹ́ sí wa.