Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 680 125.9 47.6 58.6 12.8
Aṣá. Déédéé 26,400 52.5 17.3 20.6 5.6
Aṣá. Olù. 5,673 47.9 14.0 15.9 4.2
Akéde 244,003 10.4 4.3 4.1 1.2
ÀRÒPỌ̀ 276,756 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 599
Inú wa dùn pé nígbà tí ọdún iṣẹ́ ìsìn 2005 yìí parí ní oṣù August, iye àwa akéde ti pọ̀ sí i. A ti di ẹgbàá méjìdínlógóje àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́rìndínlọ́gọ́ta [276,756] báyìí. Iye ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà tún ti pọ̀ sí i, ó ti di ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlélógún ó lé ẹgbẹ̀ẹ́dógún àti mọ́kàndínláàádọ́rin [483,069] báyìí. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún bó ṣe ń bù kún iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.