Àwọn Ibi Tá A Ó Ti Ṣe Àpéjọ Àgbègbè Ọdún 2008
Ìjọ kọ̀ọ̀kan á rí lẹ́tà tá a fi sọ àpéjọ àgbègbè tá a yàn án sí gbà. Kí ìjọ tí kò bá tíì rí lẹ́tà gbà títí di April 1, 2008, kọ̀wé sí ẹ̀ka ọ́fíìsì. Àwọn ọ̀rẹ́ tàbí mọ̀lẹ́bí rẹ ni kó o kọ̀wé sí bó o bá fẹ́ mọ àpéjọ àgbègbè tá a yàn wọ́n sí, má kọ̀wé sí ẹ̀ka ọ́fíìsì o.
September 26 sí 28
AGBOR 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGURÚTA ÀLÌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ILÉṢÀ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
JOS 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
USÚÀKỌ̀LÌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
October 3 sí 5
AGBOR 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGURÚTA ÀLÌ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ILÉṢÀ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
JOS 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
KÀDÚNÁ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
UYÓ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
USÚÀKỌ̀LÌ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
October 10 sí 12
AGBOR 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÀDÁGÌRÌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGURÚTA ÀLÌ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ILÉṢÀ 3 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
JOS 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
KÀDÚNÁ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
NUMAN 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
OYÉDE 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
UYÓ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
USÚÀKỌ̀LÌ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
October 17 sí 19
AGBOR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 3 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
ÀKÚRẸ́ 2 (Yorùbá)
ÀWÌ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÀDÁGÌRÌ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌBÀDÀN 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGURÚTA ÀLÌ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 1 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 4 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 4 (Yorùbá)
JOS 4 (Haúsá)
KÀDÚNÁ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
MAKURDI 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 4 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
NUMAN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
OYÉDE 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 3 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
UYÓ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
USÚÀKỌ̀LÌ 4 (Ìgbò)
October 24 sí 26
AGBOR 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 4 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 3 (Yorùbá)
ÀWÌ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÀDÁGÌRÌ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌBÀDÀN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGURÚTA ÀLÌ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 2 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 5 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 5 (Yorùbá)
KWALI 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MÀÌDÚGÙRI (Gẹ̀ẹ́sì)
MAKURDI 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 5 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
OYÉDE 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 4 (Ìgbò)
UYÓ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
USÚÀKỌ̀LÌ 5 (Ìgbò)
October 31 sí November 2
AGBOR 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 5 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀWÌ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÀDÁGÌRÌ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÓRÌ 1 (Gòkánà)
DÁLÙWỌ́N 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 4 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGURÚTA ÀLÌ 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 3 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 6 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 6 (Yorùbá)
ÌLỌRIN 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
KATSINA ALA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
KWALI 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
MAKURDI 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 6 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 6 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
OYÉDE 4 (Ísókó)
ÙBOGÒ 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 5 (Ìgbò)
UYÓ 5 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
USÚÀKỌ̀LÌ 6 (Ìgbò)
November 7 sí 9
AGBOR 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 6 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀWÌ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÀDÁGÌRÌ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÓRÌ 2 (Gòkánà)
DÁLÙWỌ́N 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 5 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 4 (Yorùbá)
IGURÚTA ÀLÌ 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 4 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 7 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 7 (Yorùbá)
ÌLỌRIN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
KATSINA ALA 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
KWALI 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
MAKURDI 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 7 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 7 (Yorùbá)
OYÉDE 5 (Ísókó)
ÙBOGÒ 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
UYÓ 6 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 7 (Ìgbò)
SÁRÍÀ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
November 14 sí 16
AGBOR 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 7 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 6 (Yorùbá)
ÀWÌ 5 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
BÓRÌ 3 (Kánà)
DÁLÙWỌ́N 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
ẸNÚGU 6 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 5 (Yorùbá)
IGURÚTA ÀLÌ 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN 5 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 8 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 8 (Yorùbá)
ÌLỌRIN 3 (Yorùbá)
KATSINA ALA 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
KWALI 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
MAKURDI 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 8 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 8 (Yorùbá)
OYÉDE 6 (Ísókó)
ÙBOGÒ 8 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
UYÓ 7 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 8 (Ìgbò)
SÁRÍÀ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
November 21 sí 23
AGBOR 9 (Gẹ̀ẹ́sì)
AKÁBỌ 8 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 7 (Yorùbá)
ÀWÌ 6 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 8 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
BÓRÌ 4 (Kánà)
DÁLÙWỌ́N 8 (Yorùbá)
ẸNÚGU 7 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 6 (Yorùbá)
IGURÚTA ÀLÌ 9 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
IKOT AKAN 6 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 9 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 9 (Yorùbá)
ÌLỌRIN 4 (Yorùbá)
KATSINA ALA 4 (Tífí)
KWALI 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 9 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 9 (Yorùbá)
OYÉDE 7 (Ísókó)
SÓKÓTÓ (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 9 (Ùròbò)
UYÓ 8 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 9 (Ìgbò)
November 28 sí 30
AGBOR 10 (Ìgbò)
AKÁBỌ 9 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 8 (Yorùbá)
ÀWÌ 7 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 9 (Ẹdó)
BÓRÌ 5 (Gòkánà)
DÁLÙWỌ́N 9 (Yorùbá)
ẸNÚGU 8 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 7 (Yorùbá)
IGURÚTA ÀLÌ 10 (Ìgbò)
IKOT AKAN 7 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 10 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 10 (Yorùbá)
ÌLỌRIN 5 (Yorùbá)
KATSINA ALA 5 (Tífí)
KWALI 6 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
MGBOKO UMUORIA 10 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 10 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 10 (Ùròbò)
UYÓ 9 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 10 (Ìgbò)
December 5 sí 7
AGBOR 11 (Esan)
AKÁBỌ 10 (Ìgbò)
ÀKÚRẸ́ 9 (Yorùbá)
ÀWÌ 8 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 9 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà Ti Amẹ́ríkà)
BENIN CITY 10 (Ẹdó)
BÓRÌ 6 (Kánà)
DÁLÙWỌ́N 10 (Yorùbá)
ẸNÚGU 9 (Ìgbò)
IGURÚTA ÀLÌ 11 (Ìgbò)
IKOT AKAN 8 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 11 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 11 (Yorùbá)
ÌLỌRIN 6 (Yorùbá)
KWALI 7 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 11 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 11 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 11 (Ùròbò)
UYÓ 10 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 11 (Ìgbò)
December 12 sí 14
AGBOR 12 (Ìgbò)
AKÁBỌ 11 (Ìgbò)
ÀWÌ 9 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 10 (Yorùbá)
DÁLÙWỌ́N 11 (Yorùbá)
IGURÚTA ÀLÌ 12 (Abua)
IKOT AKAN 9 (Ẹ́fíìkì)
IKOT EKPENE 12 (Ẹ́fíìkì)
MGBOKO UMUORIA 12 (Ìgbò)
ÙBOGÒ 12 (Ùròbò)
UYÓ 11 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 12 (Ìgbò)
January 9 sí 11, 2009
AGBOR 13 (Ìgbò)
AKÁBỌ 12 (Ìgbò)
ÀWÌ 10 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 11 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 13 (Ìjọ́)
UYÓ 12 (Ẹ́fíìkì)
USÚÀKỌ̀LÌ 13 (Ìgbò)
January 16 sì 18, 2009
AGBOR 14 (Ìgbò)
AKÁBỌ 13 (Ìgbò)
ÀWÌ 11 (Ẹ́fíìkì)
BÀDÁGÌRÌ 12 (Yorùbá)
UYÓ 13 (Ẹ́fíìkì)
January 23 sì 25, 2009
AGBOR 15 (Ìgbò)
BÀDÁGÌRÌ 13 (Ègùn)