ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | NEHEMÁYÀ 1-4
Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́
Bíi Ti Orí Ìwé
	455 B.C.E.
- Nísàn (Mar. sí Apr.) - 2:4-6 Nehemáyà gba àṣẹ láti tún Jerúsálẹ́mù tí wọ́n ti ń ṣe ìjọsìn tòótọ́ ní àkókò rẹ̀ kọ́ 
- Ííyà 
- Sífánì 
- Támúsì (June sí July) - 2:11-15 Nehemáyà dé Jerúsálẹ́mù nírú àkókò yìí, ó sì ṣàyẹ̀wò ògiri ìlú náà 
- Ábì (July sí Aug.) 
- Élúlì (Aug. sí Sept.) - 6:15 Wọ́n parí mímọ ògiri náà lẹ́yìn ọjọ́ méjìléláàádọ́ta [52] 
- Tíṣírì