March 28 Sí April 3
JÓÒBÙ 11-15
- Orin 111 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jóòbù Gbà Pé Àjíǹde Máa Wà”: (10 min.) - Job 14:1, 2—Jóòbù ṣe àkópọ̀ bí ìgbésí ayé àwa èèyàn ṣe rí (w15 3/1 ojú ìwé 3; w10 5/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 2; w08 3/1 ojú ìwé 3 ìpínrọ̀ 3) 
- Job 14:13-15a—Jóòbù mọ̀ pé Jèhófà kò ní gbàgbé òun (w15 8/1 ojú ìwé 5; w14 1/1 ojú ìwé 7 ìpínrọ̀ 4; w11 3/1 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 2 sí 4) 
- Job 14:15b—Jèhófà mọyì àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́ (w15 8/1 ojú ìwé 7 ìpínrọ̀ 3; w14 6/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 12; w11 3/1 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 3 sí 6) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Job 12:12—Kí nìdí tí àwọn Kristẹni tó jẹ́ àgbàlagbà fi lè ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́? (g99 8/8 ojú ìwé 19, àpótí) 
- Job 15:27—Kí ni Élífásì ní lọ́kàn nígbà tó dọ́gbọ́n sọ fún Jóòbù pé ‘ọ̀rá ni ó fi bo ojú ara rẹ̀’? (it-1 ojú ìwé 802 ìpínrọ̀ 4) 
- Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà? 
- Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí? 
 
- Bíbélì Kíkà: Job 14:1-22 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: fg ẹ̀kọ́ 13 ìpínrọ̀ 1—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
- Ìpadàbẹ̀wò:: fg ẹ̀kọ́ 13 ìpínrọ̀ 2—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: fg ẹ̀kọ́ 13 ìpínrọ̀ 3 àti 4 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (5 min.) 
- “Ìràpadà Mú Kí Àjíǹde Ṣeé Ṣe”: (10 min.) Ìjíròrò. Ní ìparí ìjíròrò yìí, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a wò ní Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Kọ́kọ́ Máa Wá Ìjọba Ọlọ́run!” ti ọdún 2014. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 12 ìpínrọ̀ 1 sí 12 (30 min.) 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 33 àti Àdúrà