ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 2
  • April 4 Sí 10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 4 Sí 10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 2

April 4 Sí 10

JÓÒBÙ 16-20

  • Orin 79 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Sọ Ọ̀rọ̀ Rere Tó Ń Gbéni Ró Tó sì Ń Fúnni Lókun”: (10 min.)

    • Job 16:4, 5​—Ó yẹ kí ọ̀rọ̀ ẹni tó ń gbani nímọ̀ràn máa gbéni ró (w90 3/15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 1 àti 2)

    • Job 19:2​—Ọ̀rọ̀ kòbákùngbé tí Bílídádì sọ sí Jóòbù mú kí Jóòbù fi ìbínú sọ̀rọ̀ (w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 6; w94 10/1 ojú ìwé 32)

    • Job 19:25​—Nígbà tí wàhálà bá Jóòbù dé góńgó, ìrètí àjíǹde tù ú nínú (w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 5; it-2 735 ojú ìwé 735 ìpínrọ̀ 2 àti 3)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Job 19:20​—Kí ni Jóòbù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé ‘bí awọ eyín mi ni mo fi yèbọ́’? (w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 1; it-2 ojú ìwé 977 ìpínrọ̀ 1)

    • Job 19:26​—Báwo ni Jóòbù ṣe “rí Ọlọ́run,” nígbà tí èèyàn kankan ò lè rí Jèhófà? (w94 11/15 ojú ìwé 19 ìpínrọ̀ 17)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: Job 19:1-23 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 42

  • “Ohun Tuntun Tá A Lè Fi Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò”: (10 min.) Ìjíròrò. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n máa lo apá tá a pè ní “Ohun Tí Bíbélì Sọ” láti fi bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò táá yọrí sí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: (5 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí. A gbé e ka Ilé Ìṣọ́ February 15, 2015, ojú ìwé 30, ìpínrọ̀ 4 sí 6.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 12 ìpínrọ̀ 13 sí 25, àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 107 (30 min.)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 65 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́