May 23 Sí 29
SÁÀMÙ 19-25
- Orin 116 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà”: (10 min.) - Sm 22:1—Ó máa dà bíi pé Ọlọ́run ti fi Mèsáyà sílẹ̀ (w11 8/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 16) 
- Sm 22:7, 8—Wọ́n máa kẹ́gàn Mèsáyà (w11 8/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 13) 
- Sm 22:18—Wọ́n máa ṣẹ́ kèké lé aṣọ Mèsáyà (w11 8/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 14) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Sm 19:14—Ẹ̀kọ́ pàtàkì wo la lè rí kọ́ nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w06 5/15 ojú ìwé 19 ìpínrọ̀ 8) 
- Sm 23:1, 2—Báwo ni Jèhófà ṣe jẹ́ olùṣọ́ àgùntàn tó nífẹ̀ẹ́ wa? (w02 9/15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 1 àti 2) 
- Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà? 
- Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sáàmù 25:1-22 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan fún onílé lórí fóònù tàbí tablet rẹ. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh—Fi ohun tá a lè fi ṣe ìwádìí, tó wà nínú JW Library wá ẹsẹ Bíbélì kan tó dáhùn ìbéèrè tí onílé béèrè. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 129 sí 130 ìpínrọ̀ 11 àti 12—Ní ṣókí, fi han ẹni tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ bó ṣe lè fi JW Library tó wà lórí fóònú tàbí tablet rẹ̀ múra ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ sílẹ̀. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Àwọn Ọ̀nà Tó O Lè Gbà Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library”—Apá Kejì: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo àwọn fídíò méjì tá a pè ní Wa Oríṣiríṣi Ìtumọ̀ Bíbélì Jáde Kó O sì Máa Lò Ó àti Ṣe Ìwádìí Nínú Bíbélì Tàbí Ìtẹ̀jáde Míì, kó o sì jíròrò wọ́n ní ṣókí. Lẹ́yìn náà, jíròrò ìsọ̀rí tó gbẹ̀yìn nínú àpilẹ̀kọ náà. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ọ̀nà míì tí wọ́n ti gbà lo JW Library lóde ẹ̀rí. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 16 ìpínrọ̀ 1 sí 15 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 139 àti Àdúrà