May 30 Sí June 5
SÁÀMÙ 26-33
- Orin 23 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Bẹ Jèhófà Pé Kó Jẹ́ Kó O Ní Ìgboyà”: (10 min.) - Sm 27:1-3—A máa ní ìgboyà tí a bá ń ronú lórí ọ̀nà tí Jèhófà gbà jẹ́ ìmọ́lẹ̀ wa (w12 7/15 ojú ìwé 22 àti 23 ìpínrọ̀ 3 sí 6) 
- Sm 27:4—Ìmọrírì tá a ní fún ìjọsìn tòótọ́ á máa fún wa lókun (w12 7/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 7) 
- Sm 27:10—Jèhófà ṣe tán láti ti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn nígbà táwọn èèyàn míì bá kọ̀ wọ́n sílẹ̀ (w12 7/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 9 àti 10) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Sm 26:6—Bíi ti Dáfídì, báwo la ṣe ń rìn yí ká pẹpẹ Jèhófà lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ? (w06 5/15 ojú ìwé 19 ìpínrọ̀ 11) 
- Sm 32:8—Àǹfààní wo la máa rí tí Jèhófà bá fún wa ní ìjìnlẹ̀ òye? (w09 6/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 3) 
- Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà? 
- Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sáàmù 32:1–33:8 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) kt—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan fún onílé lórí fóònù tàbí tablet rẹ. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi fídíò náà Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? tó wà lórí JW Library rẹ ṣe àṣefihàn bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú ẹnì kan tó o máa ń fún ní ìwé ìròyìn déédéé. Jẹ́ kí ẹni náà wo fídíò yìí. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 9—Ní ṣókí, fi han ẹni tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ bó ṣe lè fi JW Library múra ìpàdé sílẹ̀. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (15 min.) Ní àfidípò, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ tí a rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb16 ojú ìwé 112 sí 113 àti ojú ìwé 135 sí 136) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 16 ìpínrọ̀ 16 sí 29 àti àpótí tó wà lójú ìwé 142, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 144 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 16 àti Àdúrà