July 18 Sí 24
SÁÀMÙ 74-78
- Orin 110 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Máa Rántí Àwọn Iṣẹ́ Jèhófà”: (10 min.) - Sm 74:16; 77:6, 11, 12—Máa ṣàṣàrò lórí àwọn iṣẹ́ Jèhófà (w15 8/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 3 àti 4; w04 3/1 ojú ìwé 19 àti 20; w03 7/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 6 àti 7) 
- Sm 75:4-7—Lára àwọn iṣẹ́ Jèhófà ni bó ṣe yan àwọn ọkùnrin onírẹ̀lẹ̀ láti máa bójú tó ìjọ rẹ̀ (w06 7/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 2; it-1 ojú ìwé 1160 ìpínrọ̀ 7) 
- Sm 78:11-17—Máa rántí bí Jèhófà ṣe gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀ nígbà àtijọ́ (w04 4/1 ojú ìwé 21 àti 22) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Sm 78:2—Báwo ni Mèsáyà ṣe mú àsọtẹ́lẹ̀ tó wà nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣẹ? (w11 8/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 14) 
- Sm 78:40, 41—Kí ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa bí ìwà àti ìṣe wa ṣe máa ń rí lára Jèhófà? (w12 11/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 5; w11 7/1 ojú ìwé 10) 
- Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà? 
- Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 78:1-21 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.4 ojú ìwé 16—Sọ bí a ṣe ń fi ọrẹ ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ wa. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.4 ojú ìwé 16 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 5 ìpínrọ̀ 6 àti 7 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (10 min.) 
- “Jèhófà . . . Ni Ó Dá Ohun Gbogbo”: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò yìí tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo (Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ.) Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè nípa fídíò náà. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 20 ìpínrọ̀ 1 sí 13 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 73 àti Àdúrà