ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 6
  • August 22 Sí 28

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 22 Sí 28
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 6

August 22 Sí 28

SÁÀMÙ 106-109

  • Orin 2 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Fi Ọpẹ́ Fún Jèhófà”: (10 min.)

    • Sm 106:​1-3​—Jèhófà ni ọpẹ́ wa tọ́ sí (w15 1/⁠15 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 1; w02 6/1 ojú ìwé 17 sí 18 ìpínrọ̀ 19)

    • Sm 106:​7-14, 19-25, 35-39​—Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò ṣe moore sọ wọ́n di aláìnígbàgbọ́ (w15 1/⁠15 ojú ìwé 8 àti 9 ìpínrọ̀ 2 àti 3; w01 6/⁠15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 1 sí 3)

    • Sm 106:​4, 5, 48​—Ọ̀pọ̀ nǹkan ni Jèhófà ti ṣe fún wa tó yẹ ká máa dúpẹ́ fún (w11 10/⁠15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 7; w03 12/⁠1 ojú ìwé 15 àti 16 ìpínrọ̀ 3 sí 6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 109:8​—⁠Ṣé Ọlọ́run ló kádàrá Júdásì pé kó da Jésù kí àsọtẹ́lẹ̀ lè ṣẹ? (w00 12/⁠15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 20; it-1-E ojú ìwé 857 àti 858)

    • Sm 109:31​—Báwo ni Jèhófà ṣe “dúró ní ọwọ́ ọ̀tún òtòṣì”? (w06 9/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 8)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 106:​1-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 6​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 7​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 178 sí 179 ìpínrọ̀ 14 sí 16​—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 94

  • Jèhófà Á Bójú Tó Àwọn Ohun Tá A Nílò (Sm 107:⁠9): (15 min.) Ìjíròrò. Kọ́kọ́ fi fídíò tá a pé àkọlé rẹ̀ ní Jèhófà Á Bójú Tó Àwọn Ohun Tá A Nílò han àwọn ará. (Lọ sí tv.jw.org/⁠yo, kó o sì wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÌDÍLÉ.) Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ pàtàkì tí wọ́n rí kọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 22 ìpínrọ̀ 14 sí 24 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 194

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 149 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́