ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 2
  • October 3 Sí 9

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 3 Sí 9
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 2

October 3 Sí 9

ÒWE 1-6

  • Orin 37 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Fi Gbogbo Ọkàn-àyà Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Òwe.]

    • Owe 3:1-4​—Ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ kó o sì jẹ́ olóòótọ́ (w00 1/15 ojú ìwé 23 àti 24)

    • Owe 3:5-8​—Ní ìgbẹ́kẹ̀lé kíkún nínú Jèhófà (w00 1/15 ojú ìwé 24)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Owe 1:7​—Báwo ni ìbẹ̀rù Jèhófà ṣe jẹ́ “ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìmọ̀”? (w06 9/15 ojú ìwé 17 ìpínrọ̀ 1; it-2-E ojú ìwé 180)

    • Owe 6:1-5​—Ìgbésẹ̀ tó mọ́gbọ́n dání wo la lè gbé tá a bá rí i pé a ti ṣe àdéhùn tí kò mọ́gbọ́n dání lórí ọ̀rọ̀ okòwò? (w00 9/15 25-26)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 6:20-35

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Jákèjádò ayé, a máa pé àwọn èèyàn láti wá sáwọn ìpàdé wa ní òpin ọ̀sẹ̀, gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kópa kíkún nínú iṣẹ́ yìí.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 107

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.) Ẹ sì lè jíròrò ẹ̀kọ́ tá a rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb16 ojú ìwé 25 sí 27)

  • Máa Hùwà Rere Sáwọn Tó Wá sí Àwọn Ìpàdé Wa (Owe 3:27): (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? Lẹ́yìn náà béèrè pé báwo la ṣe lè túbọ̀ máa fìfẹ́ hàn sí ara wa ní Gbọ̀ngàn Ìjọba lóṣù October àti ní gbogbo ìgbà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 2 ìpínrọ̀ 1 sí 12

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 143 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́