ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 3
  • October 10 Sí 16

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 10 Sí 16
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 3

October 10 Sí 16

ÒWE 7-11

  • Orin 32 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn-àyà Rẹ Yà Bàrá”: (10 min.)

    • Owe 7:6-12​—Àwọn tí ó jẹ́ aláìní ìrírí sábà máa ń kó sínú ewu nípa tẹ̀mí (w00 11/15 ojú ìwé 29 àti 30)

    • Owe 7:13-23​—Bá a bá ṣi ìpinnu ṣe, ó lè yọrí sí wàhálà (w00 11/15 ojú ìwé 30 àti 31)

    • Owe 7:4, 5, 24-27​—Ọgbọ́n àti òye máa dáàbò bò wá (w00 11/⁠⁠15 ojú ìwé 29 àti 31)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Owe 9:7-9​—Báwo ni ìdáhùn wa nígbà tí wọ́n bá wa wí ṣe ń sọ irú ẹni tá a jẹ́? (w01 5/15 ojú ìwé 29 àti 30)

    • Owe 10:22​—Kí ni ìbùkún Jèhófà ní nínú fún wa lónìí? (w06 5/⁠⁠15 ojú ìwé 26 sí 30 ìpínrọ̀ 3 sí 16)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 8:22–9:6

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.5 tó wà lójú ìwé 2​—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.5​—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 176 ìpínrọ̀ 5 àti 6​—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 83

  • Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù (Owe 10:19): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ wo fídíò tá a pé àkọlé rẹ̀ ní Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù. Lẹ́yìn náà, jíròrò àpilẹ̀kọ tó wà pẹ̀lú rẹ̀, tá a pè àkọlé rẹ̀ ní “Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?” Tẹnu mọ́ àwọn kókó tó wà lábẹ́ ìsọ̀rí náà “Béèyàn Ṣe Ń Fọ̀rọ̀ Ránṣẹ́.”

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 2 ìpínrọ̀ 13 sí 22

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 152 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́