November 14 Sí 20
Oníwàásù 1-6
- Orin 66 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Gbádùn Gbogbo Iṣẹ́ Àṣekára Rẹ”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù.] 
- Onw 3:12, 13—Iṣẹ́ àṣekára jẹ́ ẹ̀bùn látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ó sì yẹ ká gbádùn rẹ̀ (w15 2/1 ojú ìwé 4 sí 6) 
- Onw 4:6—Máa fi ojú tó tọ́ wo iṣẹ́ rẹ (w15 2/1 ojú ìwé 6 ìpínrọ̀ 3 sí 5) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Onw 2:10, 11—Kí ni Sólómọ́nì wá mọ̀ nípa níní ọrọ̀? (w08 4/15 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 9 àti 10) 
- Onw 3:16, 17—Ojú wo ló yẹ ká máa fi wo ìwà ìrẹ́jẹ tó kúnnú ayé? (w06 11/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 9) 
- Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà? 
- Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 1:1-18 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.6 tó wà lójú ìwé 2—Fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp16.6—Ka ẹsẹ Bíbélì kan látorí fóònù tàbí tablet. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 22 àti 23 ìpínrọ̀ 11 àti 12—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? ”: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò bá a ṣe ń darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, tó dá lórí Òtítọ́ 4 lójú ìwé 115 nínú ìwé Bíbélì Kọ́ Wa, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 1 sí 6, àpótí náà “Ìtumọ̀ Orúkọ Ọlọ́run” 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 112 àti Àdúrà