April 17-23
Jeremáyà 25-28
- Orin 137 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jẹ́ Onígboyà Bíi Jeremáyà”: (10 min.) - Jer 26:2-6—Jèhófà ní kí Jeremáyà kìlọ̀ fún àwọn èèyàn pé ìparun ń bọ̀ (w09 12/1 24 ¶6) 
- Jer 26:8, 9, 12, 13—Jeremáyà ò gbà káwọn ọ̀tá kó jìnnìjìnnì bá òun (jr 21 ¶13) 
- Jer 26:16, 24—Jèhófà dáàbò bo wolìí rẹ̀ tó jẹ́ onígboyà (w09 12/1 25 ¶1) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Jer 27:2, 3—Kí ló lè fà á tí àwọn ońṣẹ́ láti oríṣiríṣi orílẹ̀-èdè fi wá sí Jerúsálẹ́mù, kí sì nìdí tí Jeremáyà fi ṣe ọ̀pá àjàgà fún wọn? (jr 27 ¶21) 
- Jer 28:11—Báwo ni Jeremáyà ṣe lo làákàyè nígbà tí Hananáyà ta kò ó, kí nìyẹn sì kọ́ wa? (jr 187-188 ¶11-12) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 27:12-22 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 7 ¶4-5—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Àwọn Orin Ìjọba Ọlọ́run Máa Ń Jẹ́ Ká Nígboyà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Orin Tó Ń Ru Àwọn Òṣìṣẹ́ Sókè. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 11 ¶9-21 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 26 àti Àdúrà