ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 29-31
Jèhófà Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Májẹ̀mú Tuntun
Bíi Ti Orí Ìwé
	Jèhófà sọ pé òun máa fi májẹ̀mú tuntun rọ́pò májẹ̀mú Òfin, èyí tó máa ṣàǹfààní títí láé.
| MÁJẸ̀MÚ ÒFIN | MÁJẸ̀MÚ TUNTUN | |
|---|---|---|
| Jèhófà àti orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì nípa tara | ÀWỌN TÓ KÀN | Jèhófà àti Ísírẹ́lì tẹ̀mí | 
| Mósè | ALÁRINÀ | Jésù Kristi | 
| Ẹran ni wọ́n fi ń rúbọ | OHUN TÓ FÌDÍ RẸ̀ MÚLẸ̀ | Jésù fi ara rẹ̀ rúbọ | 
| Wàláà òkúta | IBI TÁ A KỌ Ọ́ SÍ | Ọkàn àwọn èèyàn |