ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 32-34
Àmì Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Máa Mú Ísírẹ́lì Padà Bọ̀ Sípò
Bíi Ti Orí Ìwé
	- Jeremáyà ṣe àwọn ohun tó yẹ nígbà tó fẹ́ ra pápá. 
- Jèhófà ṣèlérí fún àwọn tó wà nígbèkùn pé tí wọ́n bá gba ìbáwí, òun máa dárí jì wọ́n, wọ́n á sì pa dà sí Ísírẹ́lì; ìyẹn fi hàn pé ẹni rere ni Jèhófà.