May 22-28
Jeremáyà 44-48
- Orin 70 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Má Ṣe ‘Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ’”: (10 min.) - Jer 45:2, 3—Èrò òdì tó gba Bárúkù lọ́kàn kó wàhálà bá a (jr 104-105 ¶4-6) 
- Jer 45:4, 5a—Jèhófà fìfẹ́ tọ́ Bárúkù sọ́nà (jr 103 ¶2) 
- Jer 45:5b—Ọlọ́run dá ẹ̀mí Bárúkù sí torí pé ó gbájú mọ́ àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù (w16.07 8 ¶6) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Jer 48:13—Kí nìdí tí ojú á fi ti àwọn ọmọ Móábù nítorí Kémóṣì? (it-1 430) 
- Jer 48:42—Kí nìdí tí àsọtẹ́lẹ̀ Jèhófà pé ìlú Móábù máa pa run fi mú kí ìgbàgbọ́ wa túbọ̀ lágbára? (it-2 422 ¶2) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 47:1-7 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 199 ¶9-10—Ní ṣókí, kọ́ akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ bó ṣe lè ṣe ìwádìí nípa ìṣòro kan tó ní. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Má Ṣe Máa Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Yín: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé—Kí Ni Mo Fẹ́ Fi Ayé Mi Ṣe?—Ìrírí. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 4—Ìjọba Ọlọ́run Jagun Mólú—A Fi Ìdí Ìhìn Rere Múlẹ̀ Lọ́nà Òfin,” orí 13 ¶1-10 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 17 àti Àdúrà