June 12-18
ÌDÁRÒ 1-5
- Orin 128 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ẹ̀mí Ìdúródeni Ń Jẹ́ Ká Ní Ìfaradà”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìdárò.] 
- Ida 3:20, 21, 24—Jeremáyà fi hàn pé òun ní ẹ̀mí ìdúródeni, ó sì gbẹ̀kẹ̀ lé Jèhófà (w12 6/1 14 ¶3-4; w11 9/15 8 ¶8) 
- Ida 3:26, 27—Tá a bá ń fara da àdánwò ìgbàgbọ́ ní báyìí, èyí á jẹ́ ká lè kojú àwọn ìṣòro tó ṣì ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú (w07 6/1 11 ¶4-5) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ida 2:17—“Àsọjáde” wo ní pàtàkì ni Jèhófà mú ṣẹ sórí Jerúsálẹ́mù? (w07 6/1 9 ¶4) 
- Ida 5:7—Ǹjẹ́ Jèhófà máa ń mú káwọn èèyàn jìyà ẹ̀ṣẹ̀ táwọn baba ńlá wọn ṣẹ̀? (w07 6/1 11 ¶1) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ida 2:20–3:12 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.3—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.3—Pe ẹni náà wá sí àwọn ìpàdé wa. 
- Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w11 9/15 9-10 ¶11-13—Àkòrí: Jèhófà Ni Ìpín Mi. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (8 min.) Tàbí kẹ́ ẹ jíròrò “Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí” tó wà nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb17 2-5) 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June 2017. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 13 ¶33-34, àpótí “Àwọn Ẹjọ́ Pàtàkì Tí A Jàre Rẹ̀ Ní Ilé Ẹjọ́ Gíga Tó Mú Ká Lè Túbọ̀ Máa Wàásù Ìjọba Ọlọ́run,” àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?” 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 100 àti Àdúrà