August 14-20
Ìsíkíẹ́lì 32-34
Orin 114 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́”: (10 min.)
Isk 33:7—Jèhófà yan Ìsíkíẹ́lì láti jẹ́ olùṣọ́ (it-2 1172 ¶2)
Isk 33:8, 9—Bí olùṣọ́ náà bá kìlọ̀ fún àwọn èèyàn, kò ní jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (w88 1/1 28 ¶13)
Isk 33:11, 14-16—Jèhófà máa dá ẹ̀mí àwọn tó bá gbọ́ ìkìlọ̀ náà sí (w12 3/15 15 ¶3)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 33:32, 33—Kí nìdí tí a fi gbọ́dọ̀ tẹra mọ́ iṣẹ́ ìwàásù náà bí àwọn kan ò bá tiẹ̀ fẹ́ gbọ́ wa? (w91 3/15 17 ¶16-17)
Isk 34:23—Báwo ni ohun tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sọ ṣe ní ìmúṣẹ? (w07 4/1 26 ¶3)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 32:1-16
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.4—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.4—Pe ẹni náà wá sáwọn ìpàdé wa.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 2 ¶9-10—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìgboyà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà, Yẹra fún Ohun Tó Lè Ba Ìdúróṣinṣin Rẹ Jẹ́—Ìbẹ̀rù Èèyàn.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 16 ¶6-17
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 117 àti Àdúrà