August 21-27
Ìsíkíẹ́lì 35-38
Orin 132 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Tó Pa Run”: (10 min.)
Isk 38:2—Ọ̀rọ̀ náà Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù túmọ̀ sí àgbájọ àwọn orílẹ̀-èdè (w15 5/15 29-30)
Isk 38:14-16—Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù máa gbéjà ko àwọn èèyàn Jèhófà (w12 9/15 5-6 ¶8-9)
Isk 38:21-23—Jèhófà máa ṣe ara rẹ̀ lógo, ó sì máa ya orúkọ rẹ̀ sí mímọ́ nígbà tó bá pa Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù run (w14 11/15 27 ¶16)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 36:20, 21—Kí ni ìdí pàtàkì tó fi yẹ ká máa hùwà rere? (w02 6/15 20 ¶12)
Isk 36:33-36—Báwo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe ní ìmúṣẹ lóde òní? (w88 9/15 24 ¶11)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 35:1-15
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 37:29—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 1:28; Ais 55:11—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.07 31-32—Àkòrí: Kí Ni Ìtúmọ̀ Ọ̀rọ̀ Náà Pé A So Ọ̀pá Méjì Pa Pọ̀ Di Ọ̀kan?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní—Ìgbàgbọ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Máa Lépa Ohun Tó Lè Mú Kó O Jẹ́ Adúróṣinṣin—Ìgbàgbọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 16 ¶18-24, àpótí “Kíkọ Òtítọ́ Lórin,” àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 119 àti Àdúrà