September 18-24
DÁNÍẸ́LÌ 1-3
- Orin 131 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Máa San Wá Lẹ́san Tá A Bá Jẹ́ Adúróṣinṣin sí I”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Dáníẹ́lì.] 
- Da 3:16-20—Àwọn ọ̀rẹ́ Dáníẹ́lì jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà nígbà tí wọ́n kojú àdánwò ńlá (w15 7/15 25 ¶15-16) 
- Da 3:26-29—Ìdúróṣinṣin wọn fi ìyìn fún Jèhófà, Jèhófà sì san wọ́n lẹ́san (w13 1/15 10 ¶13) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Da 1:5, 8—Kí nìdí tí Dáníẹ́lì àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta fi gbà pé táwọn bá jẹ oúnjẹ tí ọba gbé kalẹ̀, ó máa sọ àwọn di ẹlẹ́gbin? (it-2 382) 
- Da 2:44—Kí nìdí tí Ìjọba Ọlọ́run fi máa fòpin sí àwọn ìjọba ayé tí ère yẹn ṣàpẹẹrẹ? (w12 6/15 17, àpótí; w01 10/15 6 ¶4) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 2:31-43 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 40:22—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 15:4—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG. 
- Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w17.02 29-30—Àkòrí: Ṣé Jèhófà Ti Kọ́kọ́ Máa Ń Díwọ̀n Ohun Tá A Lè Mú Mọ́ra Kó Tó Wá Pinnu Irú Àdánwò Tó Máa Jẹ́ Kó Dé Bá Wa? 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Ìdẹwò”: (8 min.) Ìjíròrò. 
- “Jẹ́ Adúróṣinṣin Nígbà Tí Wọ́n Bá Yọ Mọ̀lẹ́bí Rẹ Kan Lẹ́gbẹ́”: (7 min.) Ìjíròrò. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 6—Ṣíṣètìlẹyìn Fún Iṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run—À Ń Kọ́ Ibi Ìjọsìn, A sì Ń Ṣèrànwọ́ Nígbà Àjálù,” orí 18 ¶1-8 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 101 àti Àdúrà