October 9-15
DÁNÍẸ́LÌ 10-12
- Orin 31 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba”: (10 min.) - Da 11:2—Àwọn ọba mẹ́rin díde ní Ilẹ̀ Ọba Páṣíà (dp 212-213 ¶5-6) 
- Da 11:4—Ìjọba Alẹkisáńdà pín sí apá mẹ́rin (dp 214 ¶11) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Da 12:3—Àwọn wo ni “àwọn tí ó ní ìjìnlẹ̀ òye,” ìgbà wo ni wọ́n sì “máa tàn bí ìtànyòò òfuurufú”? (w13 7/15 13 ¶16, àfikún àlàyé) 
- Da 12:13—Báwo ni Dáníẹ́lì ṣe máa “dìde”? (dp 315 ¶18) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 11:28-39 
APPLY YOURSELF TO THE FIELD MINISTRY
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 —Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 —Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ kí o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. 
- Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.11 5-6 ¶7-8—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà? 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Ń Fúnni Lókun: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà “Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀” Ń Fúnni Lokun. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 19 ¶8-18, àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?” 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 126 àti Àdúrà