October 23-29
HÓSÉÀ 8-14
- Orin 153 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Fún Jèhófà Ní Ohun Tó Dára Jù Lọ”: (10 min.) - Ho 14:2—Jèhófà mọyì bá a ṣe ń fi ẹnu wa yìn ín (w07 4/1 20 ¶2) 
- Ho 14:4—Jèhófà máa ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji àwọn tó ń mú irú ẹbọ ìyìn bẹ́ẹ̀ wá, ó máa ń tẹ́wọ́ gbà wọ́n, ó sì máa ń bá wọn dọ́rẹ̀ẹ́ (w11 2/15 16 ¶15) 
- Ho 14:9—Àǹfààní wà nínú ká máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà (jd 87 ¶11) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ho 10:12—Kí la lè ṣe láti jọlá ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀? (w05 11/15 28 ¶7) 
- Ho 11:1—Báwo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w11 8/15 10 ¶10) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ho 8:1-14 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-35 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-35—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé àṣàrò kúkúrú yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ, kí o sì ṣàlàyé kókó kan tí onílé sọ pé òun ò fara mọ́. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 152 ¶13-15—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Fi Ayé Rẹ Yin Jèhófà!”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Lo Ẹ̀bùn Ẹ Fún Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 20 ¶7-16, àpótí “Ìwé Kan Tó Wà Fáwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù” 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 63 àti Àdúrà